Yoruba World Centre

7 posts

Yoruba World Centre

Yoruba World Centre

@INCEYAC

International Centre for Yoruba Arts and Culture (INCEYAC).

John Paul II Building, UI Присоединился Mart 2023
16 Подписки5 Подписчики
Yoruba World Centre
Yoruba World Centre@INCEYAC·
ÀBẸ̀WÒ ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ÈDÈ YORÙBÁ LÁTI ORÍ-ÈDÈ AMẸ́RÍKÀ SÍ YORÙBÁ WORLD CENTRE. Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yìí tún ní àǹfààní láti rí àwọn nǹkan àtijọ́, àwòrán àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé tí ó wúlò fún iṣẹ́ ìwádìí àti ìmọ̀ nípa ìtàn, àṣà, èdè àti ìṣe àwa ọmọ Odùaà.
Yoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet media
Tiếng Việt
0
0
0
40
Yoruba World Centre
Yoruba World Centre@INCEYAC·
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ èdè yoruba láti Fásitì oríṣiríṣi lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ní wọ́n ṣàbẹ̀wò sì Yorùbá World Centre tí ó wà nínú ọgbà Fásitì Ìbàdàn. Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yìí ní àǹfààní láti gbọ́ orin àtijó láti ẹnu Àyànlolá Tìjání gbajúmọ̀ asun rárà /onírárà.
Yoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet media
Tiếng Việt
0
0
1
30
Yoruba World Centre
Yoruba World Centre@INCEYAC·
Flashback 2014 Flashback 2015 Flashback 2017
Yoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet media
English
0
0
1
25
Yoruba World Centre
Yoruba World Centre@INCEYAC·
TITLE: A SHORT HISTORY OF THE YORUBA PEOPLES AURTHUR: C. R. NIVEN (M.A. (OXON.), F.R.G.S.) Available @INCEYAC
Yoruba World Centre tweet mediaYoruba World Centre tweet media
English
0
0
2
24