If you have ever wished to reconnect with the grandeur, mystery and storytelling soul of precolonial Africa, this book was written for you.
ÌJÍ-ÀLÒGBÓ: The Legend of the Leopard Tamer a.co/d/3wUOzai
This historical fiction by Bode Oje takes readers into a richly imagined African past filled with adventure, statecraft, destiny, tradition and the untamed spirit of the land itself.
It is more than a story. It's a journey back into the memory of Africa, Yorùbáland in particular.
For Africans in the diaspora who still long to hear the echoes of old Africa — the Africa of clan totems, hunters, ancient kingdoms, forests, mysteries, oral legends and deep spiritual connection with nature, ÌJÍ-ÀLÒGBÓ: The Legend of the Leopard Tamer is a novel you must read.
Àmì ilẹ̀ adúlẹ́wà wà lára aṣọ wọn, ojú wọn sì ń wo ohun tó jìn ju ilẹ̀ ayé lọ — bí ẹni pé wọ́n mọ̀ pé ìrìn-àjò yìí kì í ṣe fún ìwádìí nìkan, bí kò ṣe ìbẹ̀rẹ̀ ìbánisọ̀rọ̀ tuntun láàrin ènìyàn àti àwọn ẹ̀dá inú òkùnkùn Òfurujágádo.
#FabuOnimojinle#Olojò
Nínú ọkọ̀ EGBÉ, àwọn arèràwọ̀ ilẹ̀ adúlẹ́wà kọ́kọ́ ya àwòrán ìṣọ̀kan wọn nínú àìní-òǹfà agbára-ayé. Àwòjá, Aláwòfín, Bínúpọta, Fìmọ̀ṣẹwà, Àríwòye àti àwọn yòókù ń rẹ́rìn-ín bí Ilẹ̀-ayé ṣe ń yí lọ́ lójú ferese ọkọ̀ irin-ajo náà.
#SupportSciFiYoruba
Been seeing a lot of people struggling lately… and I get it.
I’m doing a small giveaway — $100 to 10 people. No big reason other than spreading some good energy.
Reply with a 🤍 and I’ll pick randomly.
@Shork_media I will use it to establish my project Science Fiction in Mother Tongue Africa. I can send you the proposal including executive summary if you like.
láti orí àwọn àtọ́mù dé irawọ̀ àti ẹ̀dá ẹ̀mí ní Yorùbá, Igbo, Hausa, àti gbogbo èdè Áfíríkà. Kí ìfẹ́ ìmọ̀ rọ́pò ìbẹ̀rù, kí ìmòye tó jinlẹ̀ sì rọ́pò ìgbàgbọ́ aláìlójú.
STEM kì í ṣe ohun àjèjì. Ìmọ̀ kì í ṣe ohun àjèjì. Ó di tiwa nígbà tí a bá sọ ọ́ ní èdè tiwa.
Áfíríkà kì í ṣe aláìgbọ́n, aláìpé lórí tàbí aláìlóye. Ohun tí ó sábà máa ń ṣòro fún wa ni bí a ṣe lè ṣe ọgbọ́n ìmòye gidi ti yóò fi rọrùn láti lóye ìmọ̀ ìjìnlẹ̀. Èdè ni afárá náà.
Ẹ jẹ́ ká gbájúmọ́ ọgbọ́n ìsọ̀tàn ní èdè abínibí tí yóò lè ṣàlàyé ohun gbogbo;
Èyí ni ọjọ́ iwájú tí a gbọ́dọ̀ ṣe
Nígbà tí a bá kọ́ sáyẹ́ǹsì ní èdè abínibí, ó máa di ohun tó rọrùn láti lóye, tó sì sunmọ́ wa gan-an. Àwọn ọmọ kì í tún rí ara wọn gẹ́gẹ́ bí alejo nínú ìmọ̀ mọ́—wọn á ní ìmọ̀ náà, wọn á bẹ̀rẹ̀ sí í béèrè ìbéèrè.
#SupportSci
@DurovPD I will use it to establish my project Science Fiction in Mother Tongue Africa. I can send you the proposal including executive summary if you like.
I just concluded the “Revised & Expanded” version of my best Selling Book, Small Business Big Money and asked ChatGPT to come up with a cover but keep the feel of the old edition, put me in a T- shirt and generally make it interesting 😂
BREAKING NEWS!
Artemis crew captured image of President Tinubu on the far side of the moon.
Stay tuned for details of the Fàbú Onímọ̀jìnlẹ̀ News.
#SupportSciFiYoruba #ìrìnàjòsínúayédiméjì #fabuonimojinle#Yoruba#YorubaSciFi