Àdùfẹ́

2.6K posts

Àdùfẹ́ banner
Àdùfẹ́

Àdùfẹ́

@creative_adufe

• Aláròkọ ìtàn àti orin ní èdè Yorùbá • Story Builder • Scriptwriter • Virtual Assistant for Creators & Brands. 💬08069189600

Abeokuta Katılım Ekim 2025
252 Takip Edilen205 Takipçiler
Sabitlenmiş Tweet
Àdùfẹ́
Àdùfẹ́@creative_adufe·
Ọ̀DẸ̀ DÀRÚ —————— ÌṢE ÀKỌ́KỌ́ —————— Ní ilé Túndé Àlàbá: kí a má parọ́, ilé Túndé Àlàbá yìí ni a ò bá ma pè nílé owó rẹgún. Kínni ohun tóo fẹ́ tí o kò ní rí níbẹ̀ nàá? Ṣùgbọ́n…. Hmmmm Iná tàn sójú aya Túndé Àlàbá nìkan ṣoṣo nínú yàrá ìgbafẹ́ pẹ̀lú àwọn ìwé àwòrán lọ́wọ́ rẹ̀. Ojú-u- rẹ̀ fi ìgbà ìrántí àti ìbànújẹ́ hàn. Túndé Àlàbá wọlé, pẹ̀lú àpamọ́wọ́ lọ́wọ́ rẹ̀, òjú rẹ̀ kò fi ẹ̀sùn kankan hàn. Ó rí aya rẹ̀ níbi tó sórí kodò sí, ṣùgbọ́n kò sọ̀rọ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀. Túndé: (ó fi àpamọ́wọ́ rẹ̀ sílẹ̀, ń wo aya rẹ̀) o ṣì ún wo àwọn àwòrán yìí nà? Rántí: (ń sọ̀rọ̀ jẹ́jẹ́ pẹ̀lú ìmọ̀lára láì gbójú wòkè) Mò ń wo ọ̀nà tí a gbà dé ibí yìí ni. Túndé dúró síbi tí ó wà fún ìṣẹ́jú díẹ̀. Ara rẹ̀ lọ́ tìkọ̀_ẹ̀rí ọkàn ń jẹ́ẹ. Ó súnmọ́ ibi àga, ó jókòó. Ohùn rẹ̀ ń gbọ̀n. Túndé: (ń mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ́jẹ́ ) Kí… Kí lohun tí o túmọ̀ sí, nípa bí a ṣe dé ibi yìí ? Rántí: (síjú wòkè wo ọkọ rẹ̀) Mi ò mọ̀, Túndé! Níṣe ló dàbí ẹni pé... gbogbo nǹkan ti yí padà. Bí a ṣé ń ríra wa, àti bí mo ṣé ń rí ẹ... ó dà bíi ẹni pé a ò jọ gbé nínú ayé kannáà mọ́. Ara Túndé yí tìkọ̀ fún ìṣẹ́jú díẹ̀_kò mọ ohun tí yóò sọ ṣùgbọ́n ó sáré ṣe bí ọkùnrin. Túndé: (gbé ẹ̀yìn rẹ̀ le àga) wòó! Kò sí ẹni tí kìí ní àdojúkọ̀ láyé. A ti ní àwọn àdojúkọ̀ tó pọ̀ síbẹ̀ a ṣì dúró digbí. ohun tó ṣe pàtàkì náà nìyẹn. Rántí: (mirí pẹ̀lú ìbànújẹ́ ọkàn) aah! ó mà ṣe o Túndé: (pẹ̀lú ìbínú) wòó! wòó! wòó! Rántí, kì í ṣe lónìí. Jọ̀wọ́! Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ ún bọ̀ láti ibi iṣẹ́ ni o. Rántí: (ń fi ẹdùn ọkàn rẹ̀ hàn) Ṣé o rò pé mi ò mọ ohun tí o ti ń ṣe láti ọjọ́ yìí ni ? Ṣé o rò pé mi ò mọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ni? Ní ìwọ náà ? Túndé sáré dìde lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ohùn rẹ̀ ń gòkè díẹ̀-díẹ̀ bí ó ṣe ń súnmọ́ Rántí Túndé: (lójú kojú) Kí lo túmọ̀ sí yẹn? Rántí: (lójú kọjú): Ó túmọ̀ sí wípé mo mọ̀ pé ọwọ́ rẹ kò mọ́. Ó ti tọjọ́ mẹ́ta tára tí ún fu mí sí ẹ. Túndé, Kínni ohun ìkọ̀kọ̀ tí ò ń ṣe? Túndé fi ọwọ́ pa irun ìjàgbọ̀n rẹ̀, ó sì sójú kóíkóí. Ó mọ ohun tí Rántí ń sọ, ṣùgbọ́n kò ṣetán láti jẹ́wọ́. Túndé: (pẹ̀lú ògbójú) Kí lo túmọ̀ sí yẹn, Rántí? Ṣé o fẹ́ kí n bẹ̀rẹ̀ sí ní rojọ́ mọ́ra mi lésẹ̀ ni? Àbí Kínni ohun tó o fẹ́ gan? Rántí: (ó mu ní ranto, ń pariwo) Mo fẹ́ mọ̀ òtítọ́. Mo fẹ́ mọ irú ẹni tí o jẹ́ gan-an. Má fi ẹ̀jẹ̀ sínú tutọ́ funfun síta fún mi mọ́. Má tàn mí mọ́ o jàre. Ọ̀rọ̀ tí Rántí sọ yìí, mú Túndé lọ́kàn riri. Ó de eyín rẹ̀ pọ̀ mọ́ agbárí bíi kí ìjàgbọ̀n rẹ̀ fọ́ sílẹ̀ wẹ́lẹ́wẹ́lẹ́. Ṣùgbọ́n, Ọmọ akin kò gbọdọ̀ ṣe bí ojo, ó tún ṣe bíi ọkùnrin, ó ní: Túndé: (ń sọ̀rọ̀ wẹ́rẹ́) Rántí, o ò lóye. o ò mọ ǹkan kan. Ọ̀pọ̀ nǹkan ni mo ti ṣe, ọ̀pọ̀ nǹkan náà ni mo sì tú nílò láti ṣe láti dáàbò yín àti láti mú ìdílé yìí dúró ṣinṣin. Rántí: (kò gbàgbọ́) Dáàbò bò wá? àbí dáàbò bo ara rẹ? Túndé! Túndé fẹ́ fèsì, ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ sá lọ fún. Ó ń wo Rántí pẹ̀lú bí ó tií ń tiraka láti sọ ǹkankan. Rántí: (tìbínú tìbínú) Èèyàn ni mo pè ẹ́_ nítorí ẹ̀ ni mo ṣe finú tán ẹ ... ṣùgbọ́n ní bàyí, mi ò lérò bóyá mo lè fi inú tán ẹ mọ́. Túndé mọ ìwà láabi tó wà lọ́wọ́ òun síbẹ̀ kò fẹ́ juwọ́ sílẹ̀. Ọ̀rọ̀ padà jáde lẹ́nu rẹ. Ó ní: Túndé: Kínni O fẹ́ kí n wí, Rántí? Pé kíi sọ pé _mo ti ṣàṣìṣe o? Àbí kíi sọ pé mo ti ṣe ohun tí kò mórí rẹ wú? Àbí ohun tí o fẹ́ kọ́ nìyẹn ni ? Rántí: (pẹ̀lú ìbínú) Mo nílò láti gbọ́ òtítọ́, Túndé. Gbogbo òtítọ́ tó bá wà níkùn rẹ _tètè máa sọ́. Kí gbogbo ẹ, ó tó lọ́jú pọ̀ fún ẹ. Túndé: òótọ́? Rántí: Bẹ́ẹ̀ ni Túndé ń wo Rántí láì sọ ǹkan kan bẹ́ẹ̀ ni Rántí náà ń wò ó ní ìrètí èsì. Wọ́n jọ wá ún wojú ara wọn. #Adufe #Ẹ̀dáYorùbá #ÌtànYorùbá
Àdùfẹ́ tweet media
Tiếng Việt
5
10
19
724
Àdùfẹ́ retweetledi
Toke(Mrs💍)❤️👑
Toke(Mrs💍)❤️👑@Ollaitan___·
Whatever you do,stay away from women who hum!liate other women for male attention
English
9
8
27
309
Salahu
Salahu@salahudeen33·
Salahu tweet media
ZXX
3
4
20
192
Jay
Jay@Voix_of_d_north·
@creative_adufe God bless you. This was the best response so far
English
1
0
1
3
Àdùfẹ́ retweetledi
RAWSHIELD
RAWSHIELD@Rashnaking·
Me looking at the person who caught me talking to myself 😔 Mi ò yá wère o!
Ònà àbáyọ ni mo ń wá God abeg, make dem no hear the part where I insult myself 😭
English
3
3
4
75
Àdùfẹ́ retweetledi
Owolabi Abdullah Ishola
Owolabi Abdullah Ishola@AbdullahIs74903·
An Open Message to the Leadership of X To @elonmusk and @nikitabier @X This is not a complaint from one user. This is the collective voice of genuine creators who today feel unsafe, unheard, and uncertain on X. Every day, accounts are suspended and limited from visibility without clear reasons: Follow someone — risk. Post normally — risk. Engage actively — risk.
English
1
2
5
59
El’hadj Ragna
El’hadj Ragna@YinkaDerek·
Female accounts grow faster then men accounts on social media like magic. Why exactly????
English
1
0
2
38
Àdùfẹ́
Àdùfẹ́@creative_adufe·
@Alpha_Yom Let he who has ear refuse to hear👂 🏃‍♀️🏃‍♀️🏃‍♀️
English
1
1
1
12
Àdùfẹ́ retweetledi
Akitiolu 🇳🇬 🍦
No be every topic dem de put mouth No be everything dem dey use farm content or engagement Use your brain
English
2
6
7
128
Heart_007
Heart_007@kingsleyheart·
I will never unfollow you.
English
2
1
3
13
Àdùfẹ́ retweetledi
ALISH 💙
ALISH 💙@_alishprince·
Always pray for alignment. To be at the right place, at the right time, doing the right thing around the right people who will help you get to your destiny.🙏
English
0
3
5
58
Àdùfẹ́
Àdùfẹ́@creative_adufe·
@zyainy Yes, i can but the only problem here is WATER SACHET.
English
1
0
1
34
Jimoh Zainab
Jimoh Zainab@zyainy·
“As a wife can you manage 100k for food monthly for a family of 4 (2 kids, wife and husband)?
Jimoh Zainab tweet media
English
10
2
24
700
Àdùfẹ́ retweetledi
Ikemileyi
Ikemileyi@ladycarpenter01·
No GYM ❌❌❌ Take Ikeola Treats Unsweetened Greek yoghurt at least once in a day. Avoid junks, reduce oils in foods, drink enough water, eat a lot of fruits, eat your carbohydrates with a lot of vegetables. Walk for at least 30mins in the morning and evening, make sure you watch your calories intakes. You’ll lose weight accordingly, no rush, no pressure 💯 I don’t want to go below this, so I’ll be maintaining between 70-71kg now. If I can do it within 6 months, you can also do it. Just start 💪 You are welcome 🤗
Ikemileyi tweet media
Ikemileyi@ladycarpenter01

From 83KG to this in 6 months Me sef don try, I salute myself 🙌 Motherhood is not for the weak. To everyone trying to lose weight, you can do it!!! Keep trying and be dedicated 💪

English
6
19
21
300
Maryam Shuaibu Aliyu
Maryam Shuaibu Aliyu@Cyberhijabitech·
Hello world. I made it to the top 100 Nigeria LinkedIn creators 🎉💃
Maryam Shuaibu Aliyu tweet media
English
57
61
777
7.8K
Baby Zee❤️😂😂🤌🤌(Ólùkọ́ àwọn ọmọ líle)
We played a game in class where you freeze, and the moment you say a Yoruba word, you unfreeze yourself 😂 It was actually fun, she was really enjoying it. Next thing, I said let’s end the game and face business… this girl now said this to me🤣🤣 The fact that all my students see me as their agemate is funny 🤣
English
2
1
9
474