Yoruba Proverbs
13.3K posts

Yoruba Proverbs
@yoruba_proverbs
Seeks to propagate Yoruba proverbs and increase their usage thereby preserving the Yoruba language and the wisdom of the Yoruba people for posterity.
Yorubaland Katılım Ekim 2011
583 Takip Edilen248.5K Takipçiler

@yoruba_proverbs Ọmọ ti o sọ pe baba oun ko la, ti o sọ pe iya oun ko ṣe to, odi igba tio ba dagba to nda iṣẹ se
Filipino

@yoruba_proverbs Omo elede to ni enu iya ohun gun. Enu e lowa yen.
Türkçe

Ọmọ ò gbọ́n; wọ́n ní kó má ṣáà kú; kíní ńpa ni bí agọ̀? /
A child lacks wisdom, yet people pray that the child does not die prematurely — for what kills more surely than foolishness?
[Stupidity, poor judgment, recklessness, or lack of sense can be costly: foolishness is a fatal flaw; don't be presumptious: avoid making hasty judgments with incomplete information]

@OBAsCOMM @yoruba_proverbs Agba to lo mi ninu o kin pariwo abi e no pure? Yinmu.
Filipino

Ẹran kí lológìnní pa lóko tó sáré wálé tó ní ki wọ́n kó agbọ̀n bá ohun lóko? /
What game did the cat catch on the farm that made it race home demanding baskets to haul it back?
[Don't make a big fuss over little results; excessive fanfare over a trivial achievement undermines both its importance and one's judgement]

Ẹyẹ àwòdì tó ní igun kéré, ẹ ní kó bọ́ síta kò yan, bí kò bá ní bá ara rẹ̀ ní ẹ̀yìn àrò. /
Let the hawk that scorns vultures as mere small birds, dare come out in the open - if it wouldn't find itself roasted at the fireplace.
[Keep to your lane and run your own race: you don't know anyone's story; don’t let arrogance blind you to the unseen safeguards others may have]
Català

Oníìpá ìṣájú ló ba ìpá jẹ́, tó ká'rí bọ'nú tó ńsunkún, òun ló fún un lórúkọ tí kò dára; tó bá jẹ́ pé ó ńkọrin tó ńdunnú pé òun gbé ọba epon de ni, ọba ẹpọ̀n láa bá máà pè é títí di òní. /
The first man afflicted with scrotal elephantiasis doomed it by weeping and despairing; had he instead rejoiced and declared it the ultimate scrotum, the condition would have been celebrated as the greatest thing to happen to scrotums to this day.
[How we frame a situation determines how it is received; nothing is inherently good or bad, but how we define it]
Tiếng Việt

A ti í gbọ́ ni kò jẹ́ kí olè ó pọ́; kò sí ẹnì tó fẹ́ iṣẹ́ ẹ́ ṣe. /
That it comes with stigma is why thieves are few; nobody wants the hassles of working.
[Human nature inclines towards ease: most would opt for the easier route if consequences didn't exist; don't be naive: apparent virtue may be forced rather than chosen.]
English

Méjì lọkùnrin í bá lọ sí ojú ogun, ọ̀hun ni ìkẹta í bá a. /
Every man goes to war expecting two outcomes (victory or defeat), yet the third, his ruin, awaits him there.
[Don't assume you know all possible outcomes: the stakes are often higher than you imagine; don't fool yourself into thinking you've covered every risk: be humble - there may be more.]
English

Ọ̀rọ̀ tó mú baálé ilé tó fi mín kanlẹ̀ ni ọ̀dẹ̀dẹ̀, ohun náà ló mú ìyálé ilé tó fi ké bí òròmọadìyẹ. /
Whatever issue makes a man sigh heavily at home, is also what makes his wife chirps like chicks.
[A truly committed relationship comes with shared burdens and concerns: whatever touches a man touches his wife, and vice versa]
Magyar

Ẹni tí ò ní ẹbí, lò ńsọ pé tí ìlú bá lè tú, kò tú; ẹni tó bá ní ẹbí, tó ní ará ló ńronú àbò ìlú./
Only a person with no relations in a town could be indifferent to its ruin; anyone with loved ones there would seek its well-being.
[It is a truism of human nature that where our treasure is, there'll be our heart and vice versa.]
Català

Bí a bá dọ̀bálẹ̀ fún aràrá, kò ní kí a má ga tí a bá dìde /
That one prostrates to a dwarf won't stop one from attaining full height when up, again.
[You may have to contend with some indignities to achieve your objectives: it's wise to stoop low or play the fool, if necessary; sometimes, doing either is the only rational course of action]

Ọsàn tó bá fẹ́ pẹ́ lórí igi lo ǹdá ewé bojú. /
The orange fruit that wishes to remain on the orange tree must hide itself among the leaves.
[Visibility without discretion courts trouble; flaunt or boast and put yourself at needless risks; avoid being "picked off" prematurely by flying under the radar.]
English